Content-Length: 131334 | pFad | http://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cw%C3%A9_Samu%E1%BA%B9li

Ìwé Sámúẹ́lì - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Ìwé Sámúẹ́lì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ìwé Samuẹli)
Ọba Ísírẹ́lì Lórí Ìtẹ́.

Ìwé Sámúẹ́lì jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Sámúẹ́lì, ìbí rẹ̀, bí ó ti ṣe dàgbà nínú ìjọ lábẹ́ wòlíì Ọlọ́run kan Élì, tí ó sì jẹ́ láti ìgbà èwe rẹ̀ ni Ọlọ́run ti pè é. Sámúẹ́lì ni wòlíì Ísírẹ́lì tó kàn lẹ́yìn Élì, tí ó sì ń fi iṣẹ́ tí Ọlọ́run ran gba àwọn ènìyàn rẹ̀ nípa yíyàn ọba Sọ́ọ́lù gẹ́gẹ́ bí i ọba Ísírẹ́lì àkọ́kọ́. Tí ó sì tún sọ̀rọ̀ nípa àyọrísí àwon àwọn Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí i olùborí lórí àwọn Filísínì, àti ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run láti má kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀. Abbl.









ApplySandwichStrip

pFad - (p)hone/(F)rame/(a)nonymizer/(d)eclutterfier!      Saves Data!


--- a PPN by Garber Painting Akron. With Image Size Reduction included!

Fetched URL: http://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cw%C3%A9_Samu%E1%BA%B9li

Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy