Content-Length: 156565 | pFad | https://yo.wikipedia.org/wiki/T._S._Eliot

T. S. Eliot - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

T. S. Eliot

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
T. S. Eliot
T. S. Eliot in 1923 by Lady Ottoline Morrell
Iṣẹ́Poet, dramatist, literary critic
CitizenshipAmerican by birth; British from 1927
Ẹ̀kọ́A.B. in philosophy
Alma materHarvard University
Merton College, Oxford
Ìgbà1905–1965
Literary movementModernism
Notable worksThe Love Song of J. Alfred Prufrock (1915), The Waste Land (1922)
Notable awardsNobel Prize for Literature (1948), Order of Merit (1948)
SpouseVivienne Haigh-Wood (Vivien) (1915–1947); Esmé Valerie Fletcher (1957 until his death)
Childrennone

Signature

Thomas Stearns Eliot OM (Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹsán Ọdún 1888 – Ọjọ́ kẹrìn Oṣù kínín Ọdún 1965) jẹ́ akéwì ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, oǹkọ̀wé eré-oníṣe àti olóríkínniwí lítíréṣò. Wọ́n gbàá bí ọ̀kan nínú àwọn akéwì pàtàkì ní ogún orundún sẹ́yìn[3] àti ẹni bí aṣíwájú fún ẹgbẹ́ ìrinkankan ìṣe òdeòní nínú ewì. Ní odún 1948 ó gba Ebun Nobeli nínú Lítíréṣọ̀. Nínú àwọn isẹ́ owọ́ rẹ̀ ni a ti lè rí Orin ololufe J. Alfred Prufrock (1910), Ile Ahoro (1922), Ese-orin merin (1945)[4] ati ere ori-itage Ipaniyan ninu Soosi (1935)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Hart Crane (1899-1932)
  2. Influences by Seamus Heaney, Bostonreview.net, accessed August 3, 2009.
  3. Collini, Stefan. I cannot go on, The Guardian, November 7, 2009.
  4. Thomas Stearns Eliot, Encyclopaedia Britannica, accessed November 7, 2009.










ApplySandwichStrip

pFad - (p)hone/(F)rame/(a)nonymizer/(d)eclutterfier!      Saves Data!


--- a PPN by Garber Painting Akron. With Image Size Reduction included!

Fetched URL: https://yo.wikipedia.org/wiki/T._S._Eliot

Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy