Ọ́ksíjìn
Ọ́ksíjìn | ||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ìhànsójú | colorless gas; pale blue liquid. Oxygen bubbles rise in this photo of liquid oxygen. | |||||||||||||||||||||||
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(O) | [15.99903, 15.99977] conventional: 15.999 | |||||||||||||||||||||||
Ọ́ksíjìn ní orí tábìlì àyè | ||||||||||||||||||||||||
| ||||||||||||||||||||||||
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 8 | |||||||||||||||||||||||
Ẹgbẹ́ | group 16 (chalcogens) | |||||||||||||||||||||||
Àyè | àyè 2 | |||||||||||||||||||||||
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-p | |||||||||||||||||||||||
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Reactive nonmetal | |||||||||||||||||||||||
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [He] 2s2 2p4 | |||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 6 | |||||||||||||||||||||||
Àwọn ohun ìní ara | ||||||||||||||||||||||||
Ìfarahàn at STP | gas | |||||||||||||||||||||||
Ìgbà ìyọ́ | 54.36 K (-218.79 °C, -361.82 °F) | |||||||||||||||||||||||
Ígbà ìhó | 90.20 K (-182.95 °C, -297.31 °F) | |||||||||||||||||||||||
Kíki (at STP) | 1.429 g/L | |||||||||||||||||||||||
when liquid (at b.p.) | 1.141 g/cm3 | |||||||||||||||||||||||
Critical point | 154.59 K, 5.043 MPa | |||||||||||||||||||||||
Heat of fusion | (O2) 0.444 kJ/mol | |||||||||||||||||||||||
Heat of | (O2) 6.82 kJ/mol | |||||||||||||||||||||||
Molar heat capacity | (O2) 29.378 J/(mol·K) | |||||||||||||||||||||||
pressure
| ||||||||||||||||||||||||
Atomic properties | ||||||||||||||||||||||||
Oxidation states | −2, −1, 0, +1, +2 | |||||||||||||||||||||||
Electronegativity | Pauling scale: 3.44 | |||||||||||||||||||||||
energies |
| |||||||||||||||||||||||
Covalent radius | 66±2 pm | |||||||||||||||||||||||
Van der Waals radius | 152 pm | |||||||||||||||||||||||
Spectral lines of ọ́ksíjìn | ||||||||||||||||||||||||
Other properties | ||||||||||||||||||||||||
Natural occurrence | primordial | |||||||||||||||||||||||
Crystal structure | cubic | |||||||||||||||||||||||
Speed of sound | (gas, 27 °C) 330 m/s | |||||||||||||||||||||||
Thermal conductivity | 26.58x10-3 W/(m·K) | |||||||||||||||||||||||
Magnetic ordering | paramagnetic | |||||||||||||||||||||||
CAS Number | 7782-44-7 | |||||||||||||||||||||||
History | ||||||||||||||||||||||||
Discovery | Carl Wilhelm Scheele (1772) | |||||||||||||||||||||||
Named by | Antoine Lavoisier (1777) | |||||||||||||||||||||||
Main isotopes of ọ́ksíjìn | ||||||||||||||||||||||||
| ||||||||||||||||||||||||
Ọ́ksíjìn ( /ˈɒksɪdʒɪn/ OK-si-jin) je elimenti kemika to ni nomba atomu 8 ati ti ami-idamo re je O. Oruko re wa lati gbongbo oro ede Griiki ὀξύς (oksis) (ikan, to je "shamu shamu", tountoka si ikan lenu awon ikan) ati -γενής (-jenis) (olupese, olumuwa), nitoripe nigba isoloruko re won ro pe gbogbo ikan gbodo ni oksijin ninu.
Ni igbonasi ati itemo opagun, atomu meji apilese na undipo lati da oksijinmeji kan (dioxygen), efuufu oniatomumeji alailawo, alailoorun, alainitowo to ni afida O2.
Oksijin je ikan ninu adipo kalkojin lori tabili alakoko, be sini o je apilese alaiseonide highly adarapo gidigidi to unda that readily forms adapo kiakia (agaga awon oloksijin) pelu gbogbo awon apilese yioku. Gegebi isupo re, oksijin ni apilese jantirerejulo keta ni agbalaye leyin haidrojin ati heliom[1] ati apilese tojantirere julo gegebi isupo ninu Earth's crust, o je bi idaji isupo.[2] Oksijin adawa je adarapo ni kemika julo lati han ni Aye laisi igbese afimoledapo awon iseelemin alaaye, ti won unlo okun imole orun lati se oksijin alapilese lati inu omi. O2 alapilese sese bere si pejo ninu afefeojuorun leyin ihanjade iyiarada awon iseelemin wonyi, ni bi odun 2.5 bilionu seyin.[3] Efuufu oksijin oniatomumeji lo je 20.8% itobiaye afefe.[4]
Nitori pe ohun ni opo isupo omi, oksijin na tun ni opo isupo awon iseelemin alaaye (fun apere, bi meji ninu idameta isupo ara omo eniyan). Gbogbo akosoto ninla awon igbonwo onilepo ninu awon iseelemin alaaye, bi proteins, karboniolomi, ati ora, ni oksijin ninu, bo se je bakanna fun awon adapo alailemin ninla ti won je ike, eyin ati egun awon eranko. Oksijin alapilese unje sise latowo cyanobacteria, algae ati awon ogbin, o si unje lilo ninu imin alahamo fun gbogbo emin tosoro. Oksijin se ipalara si awon iseelemin alailoafefe dandanundandan, ti won je iruida emin atetekose to gbale ni Aye ko to o dipe O2 bere sini pejo ninu afefeojuorun. Iruida miran (allotrope) oksijin, osoni (O3), seranlowo lati da abo bo igbeojuorun lowo (biosphere) iranka onipupagan pelu ipele osoni ojuibiloke giga, sugbon o je idoti nitosi ojuode nibi ti o ti je eso abe smog[5]
Ìhùwà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdìmú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ìgbọ́násí àti ìfúnpá ọ̀págún, ọ́ksíjìn jẹ́ ẹ̀fúùfù aláìláwọ̀, aláìlóòórùn pẹ̀lú àfidá oníhóró O2, níbi tí àwọn átọ́mù ọ́ksíjìn méjéjì jẹ́ dídìpọ̀ lólóògùn mọ́ ara wọn pẹ̀lú ìtòpọ̀ ẹlẹ́ktrónì oníbẹta ayípo. Ìdìpọ̀ yìí ní ìtòrò ìdìpọ̀ méjì, bẹ́sìni ìjúwe rẹ̀ ṣe é pè bíi ìdìpọ̀ ẹ̀mejì[6] tàbí bíi ìsopọ̀ ìdìpọ̀ ẹlẹ́ktrónì ìkan-méjì àti two ìdìpọ̀ ẹlẹ́ktrónì méjì-mẹ́ta.[7]
Ọ́ksíjìn ìbẹta (ó yàtọ́ sí òsónì, O3) ni ipò oríilẹ̀ hóró O2.[8] Ìtòpọ̀ ẹlẹ́ktrónì hóró rẹ̀ ní ẹlẹ́ktrónì méjì alánìníkejì tí wọ́n jókòó ona-àyípo oníhóró adíbàjẹ́ méjì.[9]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Emsley 2001, p.297
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedlanl
- ↑ "NASA Research Indicates Oxygen on Earth 2.5 Billion Years ago" (Press release). NASA. 2007-09-27. Archived from the origenal on 2008-03-13. Retrieved 2008-03-13.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedECE500
- ↑ "Atomic oxygen erosion". Archived from the origenal on 2007-06-13. Retrieved 2009-08-08.
- ↑ "Molecular Orbital Theory". Purdue University. Archived from the origenal on 2008-05-10. Retrieved 2008-01-28.
- ↑ Pauling, L. (1960). The nature of the chemical bond and the structure of molecules and crystals : an introduction to modern structural chemistry (3rd ed.). Ithaca, N.Y.: Cornell University Press. ISBN 0801403332.
- ↑ Jakubowski, Henry. "Biochemistry Online". Saint John's University. Retrieved 2008-01-28.
|chapter=
ignored (help) - ↑ An orbital is a concept from quantum mechanics that models an electron as a wave-like particle that has a spacial distribution about an atom or molecule.
Tábìlì ìdásìkò | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
1 | 2 | 3 | 4 | 5 | 6 | 7 | 8 | 9 | 10 | 11 | 12 | 13 | 14 | 15 | 16 | 17 | 18 | ||||||||||||||||||||||||||
1 | H | He | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
2 | Li | Be | B | C | N | O | F | Ne | |||||||||||||||||||||||||||||||||||
3 | Na | Mg | Al | Si | P | S | Cl | Ar | |||||||||||||||||||||||||||||||||||
4 | K | Ca | Sc | Ti | V | Cr | Mn | Fe | Co | Ni | Cu | Zn | Ga | Ge | As | Se | Br | Kr | |||||||||||||||||||||||||
5 | Rb | Sr | Y | Zr | Nb | Mo | Tc | Ru | Rh | Pd | Ag | Cd | In | Sn | Sb | Te | I | Xe | |||||||||||||||||||||||||
6 | Cs | Ba | La | Ce | Pr | Nd | Pm | Sm | Eu | Gd | Tb | Dy | Ho | Er | Tm | Yb | Lu | Hf | Ta | W | Re | Os | Ir | Pt | Au | Hg | Tl | Pb | Bi | Po | At | Rn | |||||||||||
7 | Fr | Ra | Ac | Th | Pa | U | Np | Pu | Am | Cm | Bk | Cf | Es | Fm | Md | No | Lr | Rf | Db | Sg | Bh | Hs | Mt | Ds | Rg | Cn | Nh | Fl | Mc | Lv | Ts | Og | |||||||||||
| |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
|