Àwọn agbègbè African Union
Ìrísí
Ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ Àtòjọ àwọn agbègbè ní Áfríkà.
African Union (AU) pín àwọn orílẹ̀ èdè tó jẹ́ ara rẹ̀ sí márùn-ún.[1] Wọ́n ti ka àwọn ọmọ Àwùjọ Áfríkà, èyí tó jẹ́ àwọn ọmọ Áfríkà ṣùgbọ́n tí wọn ń gbé ní orílẹ̀ míràn bi Amẹ́ríkà, Australia, Asia, àti Europe, gẹ́gẹ́ bi àgbègbè Africa Union kẹfà.[2]
Àtòjọ àwọn agbègbè Africa Union
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àríwá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]# | Àwọn orílẹ̀ èdè níbẹ̀ | Olú ìlú wọn | Ilẹ̀ wọn (km2) |
---|---|---|---|
1 | Algeria | Algiers | 2,381,740 |
2 | Egypt | Cairo | 1,001,451 |
3 | Àdàkọ:LBY | Tripoli | 1,759,540 |
4 | Àdàkọ:MAR | Rabat | 446,550 |
5 | Àdàkọ:SADR (Western Sahara) | El Aaiún (proclaimed) | 266,060 |
6 | Tunisia | Tunis | 163,610 |
Gúúsù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]# | Àwọn Orílẹ̀ ède níbè | (Àwọn) Olú-ìlú wọn | Ilẹ̀ wọn (km2) |
---|---|---|---|
1 | Àdàkọ:ANG | Luanda | 1,246,700 |
2 | Àdàkọ:BOT | Gaborone | 581,726 |
3 | Eswatini | Mbabane | 17,364 |
4 | Àdàkọ:LES | Maseru | 30,355 |
5 | Màláwì | Lilongwe | 118,484 |
6 | Àdàkọ:MOZ | Maputo | 801,590 |
7 | Namibia | Windhoek | 824,116 |
8 | Gúúsù Áfríkà | Pretoria Cape Town Bloemfontein |
1,221,037 |
9 | Àdàkọ:ZMB | Lusaka | 752,618 |
10 | Àdàkọ:ZIM | Harare | 390,757 |
Ìlà oòrùn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]# | Àwọn Orílẹ̀ ède níbè | Olú-ìlú wọn | Ilẹ̀ wọn (km2) |
---|---|---|---|
1 | Kòmórò | Moroni | 2,235 |
2 | Djìbútì | Djibouti | 23,200 |
3 | Ẹritrẹ́à | Asmara | 117,600 |
4 | Ethiopia | Addis Ababa | 1,104,300 |
5 | Kenya | Nairobi | 580,367 |
6 | Àdàkọ:MAD | Antananarivo | 587,041 |
7 | Àdàkọ:MRI | Port Louis | 2,040 |
8 | Àdàkọ:RWA | Kigali | 26,798 |
9 | Àdàkọ:SEY | Victoria | 451 |
10 | Somalia | Mogadishu | 637,661 |
11 | Àdàkọ:SSD | Juba | 619,745 |
12 | Àdàkọ:SUD | Khartoum | 1,886,068 |
13 | Tanzania | Dodoma | 945,087 |
14 | Àdàkọ:UGA | Kampala | 236,040 |
Ìwọ̀ oòrùn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]# | Àwọn Orílẹ̀ ède níbè | Olú-ìlú wọn | Ilẹ̀ wọn (km2) |
---|---|---|---|
1 | Benin | Porto-Novo | 112,622 |
2 | Bùrkínà Fasò | Ouagadougou | 274,000 |
3 | Àdàkọ:Country data Cabo Verde | Praia | 4,033 |
4 | Côte d'Ivoire | Yamoussoukro | 322,462 |
5 | Gambia | Banjul | 10,380 |
6 | Ghana | Accra | 238,534 |
7 | Àdàkọ:GNB | Bissau | 36,125 |
8 | Guinea | Conakry | 245,857 |
9 | Àdàkọ:LBR | Monrovia | 111,369 |
10 | Àdàkọ:MRT | Nouakchott | 1,030,700 |
11 | Mali | Bamako | 1,240,192 |
12 | Niger | Niamey | 1,267,000 |
13 | Nàìjíríà | Abuja | 923,768 |
14 | Àdàkọ:SEN | Dakar | 196,723 |
15 | Àdàkọ:SLE | Freetown | 71,740 |
16 | Togo | Lomé | 56,785 |
Àríwá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]# | Àwọn Orílẹ̀ ède níbè | Olú-ìlú wọn | Ilẹ̀ wọn (km2) |
---|---|---|---|
1 | Burundi | Gitega | 27,834 |
2 | Cameroon | Yaounde | 475,442 |
3 | Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà | Bangui | 622,984 |
4 | Chad | N'Djamena | 1,284,000 |
5 | Congo Republic | Brazzaville | 342,000 |
6 | Àdàkọ:Country data DR Congo | Kinshasa | 2,345,409 |
7 | Guinea Alágedeméjì | Malabo | 28,051 |
8 | Gabon | Libreville | 267,667 |
9 | Àdàkọ:STP | São Tomé | 964 |
Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Appendix 1: AU Regions, Strengthening PoPular ParticiPation in the African Union" (PDF). OSISA and Oxfam. 2009. p. 62. Archived from the original (PDF) on 27 September 2013. Retrieved 2 February 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Kamei, Seraphina (2011). "Diaspora as the 'Sixth Region of Africa': An Assessment of the African Union Initiative, 2002–2010". Diaspora Studies 4 (1): 61. doi:10.1080/09739572.2011.10597353. https://www.tandfonline.com/doi/abs/10.1080/09739572.2011.10597353.