Jump to content

Julie Benz

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Julie Benz ní FedCon ti ọdún 2016

Julie Marie Benz ( Ojo Ibi ojo kini osu karun ,1972) osere birin ile Amerika, ti a mo si Darla ninu Buffy the Vampire Slayer ati Angel (1997–2004) ati Rita Bennett ninu Dexter (2006–2010), ninu eyi ti o ti gba ami eye satelaiti fun Osere birin ti oni ifowosopo ni odun 2006 ati ami eye Satun ni 2009. O ko pa ninu Roswell series (1999–2000), Desperate Housewives (2010), ( Ko si ebi lasan)No Ordinary Family (2010–2011), (Okunrin to le bun) The Gifted Man (2011–2012),Defiance (2013–2015), and Hawaii Five-0 (2015-present). Awon Ipa re niyi Jawbreaker (1999), The Brothers (2001), Rambo , Saw V and Punisher: War Zone (2008), The Boondock Saints II: All Saints Day (2009), and Bedrooms (2010).

A bi Julie Marie Benz niPittsburgh , Pennsylvania , o dagba ni Murrysville , o pari eko giga re ni Ile Eko Giga Franklin.[1]Pennsylvania[2][3] Iya re nii, Joanne Marie (Elero born Seemiller), was a skater figure, and Baba re ni, George Benz, Jr., dokita onise abe ni Pittsburgh.[4] Awon ebi re tedo si eba Murrysville nigbati Benz je omo odun meji, and she started ice skating when Oun se ayarabi asa lori yin yin ni omo odun meta. she was three.[5] O se ifiga gbaga nii 1988 US osi kese jari; ni pa eko giga ipele ninu ijo jijo lori yinyin pelu eni keji re ti amo si, David Schilling, ti won si pari si ipo ketala.[6][7] Nigbatii Benz pe omo odun merinla, o kan lese otun ti ko je ki ole ko pa mo.

pFad - Phonifier reborn

Pfad - The Proxy pFad of © 2024 Garber Painting. All rights reserved.

Note: This service is not intended for secure transactions such as banking, social media, email, or purchasing. Use at your own risk. We assume no liability whatsoever for broken pages.


Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy